Good morning, Ẹ káàrọ̀, Good afternoon, Ẹ kásàán, Good evening (Early evening), Ẹ kúrọ̀lẹ́, Good evening (Late evening), Ẹ káalẹ́, Good night, Ó dàárọ̀, Hello, Ẹ ǹlẹ́, I am home!, Ẹ kú ilé, Welcome, Ẹ káàbọ̀, Congratulations, Ẹ kú orí ire, I am happy to meet you, Inú mi dùn láti rí yin, Do not be angry, Ẹ má bínú, Sorry/Take care, Pẹ̀lẹ́, Goodbye, Ó dàbọ̀, Well done, Ẹ kú iṣẹ, Please, Ẹ jọ̀wọ́, Thank you, Ẹ ṣé, How are you?, Báwo ni?, I am fine, Mo wà dáadáa/ Dáadáa ni, How is the family?, Àwọn ẹbí ńkọ́?, They are fine, Wọ́n wà dáadáa.

Leaderboard

See top players

Leaderboard

Visual style

Mga Option

I-switch ang template

Leaderboard

See top players
)
I-restore ang gi-autosave: ?