Báwo ni?, Dáadáa ni, Ṣé o wà pa?, Mo wà pa, Kíni orúkọ ẹ?, Orúkọ mi ni Tayọ̀, Ọmọ ìlú wo ni ẹ́?, Ọmọ Chicago ní Illinois ni mí, Níbo lò ń gbé?, Mò ń gbé ní Indianapolis ní Indiana, Ṣé o sùn dáadáa?, A dúpẹ́, Ó tọ́jọ́ mẹ́ta, Ọjọ́ kan pẹ̀lú, morning, Káàárọ̀, Night, Káalẹ́, Níbo ni wọ́n bí ẹ sí?, Wọ́n bí mi sí Nigeria, Níbo ni o gbé dàgbà?, Mo dàgbà sí Washington DC, Ṣé dáadáa ni, Dáadáa ni. A dúpẹ́

Leaderboard

Visual style

Options

Switch template

Continue editing: ?